1 Sámúẹ́lì 13:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òmíràn gba ọ̀nà Bẹti-Hórónì, ẹ̀kẹ́ta sí ìhà ibodè tí ó kọjú sí àfonífojì Ṣébóímù tí ó kọjú sí ijù.

1 Sámúẹ́lì 13

1 Sámúẹ́lì 13:8-19