1 Sámúẹ́lì 10:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sámúẹ́lì ṣàlàyé fún àwọn ènìyàn àwọn ìlànà ìjọba. Ó kọ wọ́n sínú ìwé, ó sì fi lélẹ̀ níwájú Olúwa. Lẹ́yìn náà, Sámúẹ́lì tú àwọn ènìyàn ká olúkúlùkù sí ilé e rẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 10

1 Sámúẹ́lì 10:21-27