1 Sámúẹ́lì 10:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sámúẹ́lì sọ fún gbogbo àwọn ènìyàn pé, “Ṣé ẹ ti ri ọkùnrin tí Olúwa ti yàn? Kò sí ẹnìkan bí i rẹ̀ láàárin gbogbo àwọn ènìyàn.”Nígbà náà àwọn ènìyàn kígbe pé, “Kí ẹ̀mí ọba kí ó gùn!”

1 Sámúẹ́lì 10

1 Sámúẹ́lì 10:17-27