1 Sámúẹ́lì 1:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Élì dáhùn pé, “Má a lọ ní àlàáfíà, kí Ọlọ́run Ísírẹ́lì fi ohun tí ìwọ ti béèrè ní ọwọ́ rẹ̀ fún ọ.”

1 Sámúẹ́lì 1

1 Sámúẹ́lì 1:16-20