1 Sámúẹ́lì 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hánà ń gbàdúrà láti inú ọkàn rẹ̀, ṣùgbọ́n ètè rẹ̀ ni ó ń mì, a kò gbọ́ ohùn rẹ̀. Élì rò wí pé ó ti mu ọtí yó.

1 Sámúẹ́lì 1

1 Sámúẹ́lì 1:10-14