1 Sámúẹ́lì 1:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó sì ṣe ń gbàdúrà sí Olúwa, Élì sì kíyèsí ẹnu rẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 1

1 Sámúẹ́lì 1:3-15