1 Pétérù 5:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kọ ojú ìjà sí i pẹ̀lú ìdúró ṣinṣin nínú ìgbàgbọ́, bí ẹ̀yin ti mọ̀ pé ìyà kan-náà ni àwọn ará yín tí ń bẹ nínú ayé ń jẹ.

1 Pétérù 5

1 Pétérù 5:1-14