1 Pétérù 5:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ máa wà ni àìrékọjá, ẹ máa ṣọ́ra; nítorí Èṣù ọ̀ta yín, bí kínnìún tí ń ke ramúramù, o ń rìn káàkiri, ó ń wa ẹni tí yóò pajẹ.

1 Pétérù 5

1 Pétérù 5:1-10