1 Ọba 8:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti Sólómónì ọba, àti gbogbo ìjọ ènìyàn tí ó péjọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀ níwájú àpótí-ẹ̀rí, wọ́n ń fi ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àgùntàn àti màlúù tí a kò le mọ iye, àti tí a kò le kà rúbọ.

1 Ọba 8

1 Ọba 8:2-11