1 Ọba 8:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

wọ́n sì gbé àpótí-ẹ̀rí Olúwa àti àgọ́ àjọ ènìyàn àti gbogbo ohun èlò mímọ́ tí ó wà nínú àgọ́. Àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì sì gbé wọn gòkè wá,

1 Ọba 8

1 Ọba 8:1-5