1 Ọba 6:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnu-ọ̀nà yàrá ìṣàlẹ̀ sì wà ní ìhà gúṣù ilé náà; wọ́n sì fi àtẹ̀gùn tí ó lórí gòkè sínú yàrá àárin, àti láti yàrá àárin bọ́ sínú ẹ̀kẹ́ta.

1 Ọba 6

1 Ọba 6:7-17