1 Ọba 6:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní kíkọ́ ilé náà, òkúta tí a ti gbẹ́ sílẹ̀ kí a tó mú-un wá ibẹ̀ nìkan ni a lò, a kò sì gbúròó òòlù tàbí àáké tàbí ohun èlò irin kan nígbà tí a ń kọ́ ọ lọ́wọ́.

1 Ọba 6

1 Ọba 6:1-11