1 Ọba 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìránṣẹ́ rẹ nìyí láàrin àwọn ènìyàn tí o ti yàn, àwọn ènìyàn ńlá, wọ́n pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ tí a kò sì lè kà wọ́n tàbí mòye wọn.

1 Ọba 3

1 Ọba 3:1-15