1 Ọba 3:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nísinsìnyìí, Olúwa Ọlọ́run mi, o ti mú ìránṣẹ́ rẹ jọba ní ipò Dáfídì baba mi. Ṣùgbọ́n ọmọ kékeré ni mí, èmi kò sì mọ̀ bí mo ṣe lè ṣe àwọn ojúṣe mi.

1 Ọba 3

1 Ọba 3:3-17