1 Ọba 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní Gíbíónì Olúwa fi ara han Sólómónì lójú àlá ní òru, Ọlọ́run sì wí pé, “Béèrè fún ohunkóhun tí o bá ń fẹ́ kí èmi ó fi fún ọ.”

1 Ọba 3

1 Ọba 3:1-10