1 Ọba 3:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì lọ sí Gíbíónì láti rúbọ, nítorí ibẹ̀ ni ibi gíga tí ó ṣe pàtàkì jù, Sólómónì sì rú ẹgbẹ̀rún ọrẹ ẹbọ sísun lórí pẹpẹ.

1 Ọba 3

1 Ọba 3:3-14