1 Ọba 2:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì pàṣẹ fún Bénáyà pé, “Ṣe bí ó ti wí. Kọ lù ú, kí o sì sin ín, kí o sì mú ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ kúrò lọ́dọ̀ mi àti kúrò lọ́dọ̀ ilé bàbá mi, tí Jóábù ti ta sílẹ̀.

1 Ọba 2

1 Ọba 2:27-38