1 Ọba 2:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì sọ fún Sólómónì ọba pé Jóábù ti sá lọ sínú àgọ́ Olúwa àti pé ó wà ní ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ. Nígbà náà ni Sólómónì pàṣẹ fún Bénáyà ọmọ Johóíadà pé, “Lọ, kí o sì kọlù ú.”

1 Ọba 2

1 Ọba 2:25-31