1 Ọba 15:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábíjà sì sùn pẹ̀lú àwọn bàbá rẹ̀, a sì sin ín ní ìlú Dáfídì. Áṣà ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

1 Ọba 15

1 Ọba 15:4-10