1 Ọba 15:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níti ìyókù ìṣe Ábíjà, àti gbogbo èyí tí ó ṣe, a kò há kọ wọ́n sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba Júdà? Ogun sì wà láàrin Ábíjà àti Jéróbóámù.

1 Ọba 15

1 Ọba 15:1-13