1 Ọba 14:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyòókù ìṣe Jéróbóámù, bí ó ti jagun, àti bí ó ti jọba, ni a kọ sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba Ísírẹ́lì.

1 Ọba 14

1 Ọba 14:17-28