1 Ọba 13:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ padà, ìwọ sì ti jẹ oúnjẹ, ìwọ sì ti mu omi níbi tí ó ti sọ fún ọ pé kí ìwọ kí ó má ṣe jẹ oúnjẹ tàbí mu omi. Nítorí náà, a kì yóò sin òkú rẹ sínú ibojì àwọn baba rẹ.’ ”

1 Ọba 13

1 Ọba 13:18-25