1 Ọba 13:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì kígbe sí ènìyàn Ọlọ́run tí ó ti Júdà wá wí pé, “Báyìí ni Olúwa wí: ‘Ìwọ ti ba ọ̀rọ̀ Olúwa jẹ́, ìwọ kò sì pa àṣẹ tí Olúwa Ọlọ́run rẹ fi fún ọ mọ́.

1 Ọba 13

1 Ọba 13:13-24