1 Kọ́ríńtì 9:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin kò mọ̀ pé, olúkúlùkù ẹni tí ó ní ipa nínú rẹ̀ ni ó máa ń sáré, ṣùgbọ́n ẹnìkan ṣoṣo ni ń gba ipò kìn-ín-ní. Nítorí náà, ẹ sá eré ìje yín kí ẹ baà le borí.

1 Kọ́ríńtì 9

1 Kọ́ríńtì 9:23-25