1 Kọ́ríńtì 9:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ṣe èyí láti lè rí ààyè láti wàásù ìyìn rere sí wọn àti fún ìbùkún tí èmi pàápàá ń rí gbà, nígbà tí mo bá rí i pé wọ́n di ọmọ-ẹ̀yìn Kírísítì.

1 Kọ́ríńtì 9

1 Kọ́ríńtì 9:18-27