1 Kọ́ríńtì 7:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àwọn tí ń sọkún, bí ẹni pé wọn kò sọkún rí, àti àwọn tí ń yọ̀ bí ẹni pé wọn kò yọ̀ rí, àti àwọn tí ń rà bí ẹni pé wọn kò ní rí,

1 Kọ́ríńtì 7

1 Kọ́ríńtì 7:27-36