1 Kọ́ríńtì 7:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ti mo ń wí ará, ni pé kúkúrú ni àkókò, láti ìsinsinyìí lọ, ẹni tí ó ni aya kí ó dàbí ẹni tí kò ní rí;

1 Kọ́ríńtì 7

1 Kọ́ríńtì 7:28-38