1 Kọ́ríńtì 6:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ nísinsinyìí, àbùkù ni fún un yín pátapáta pé ẹ̀yin ń bá ara yín ṣe ẹjọ́. Kí ní ṣe tí ẹ kò kúkú gba ìyà? Kí ní dé tí ẹ kò kúkú gba ìrẹ́jẹ kí ẹ sì fi i sílẹ̀ bẹ́ẹ̀?

1 Kọ́ríńtì 6

1 Kọ́ríńtì 6:4-8