1 Kọ́ríńtì 5:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lóòtọ́ èmi kò sí láàrin yín, ṣùgbọ́n mo wà lọ́dọ̀ yín nínú ẹ̀mí àti pé, ní orúkọ Olúwa Jésù Kírísítì, mo tí ṣe ìdájọ̀ lórí irú ẹni bẹ́ẹ̀, bí ẹni pé mo wá láàrin yín.

1 Kọ́ríńtì 5

1 Kọ́ríńtì 5:1-10