1 Kọ́ríńtì 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin ń se ìgberaga, kí ni ṣe tí ojú kò tì yín, kí ẹ sì kún fún ìbànújẹ́, kí ẹ sì rí i pé ẹ yọ ọkùnrin náà tí ó hu ìwà yìí kúrò láàrin àwọn ọmọ ìjọ yín?

1 Kọ́ríńtì 5

1 Kọ́ríńtì 5:1-6