1 Kọ́ríńtì 15:57 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ọpẹ́ ní fún Ọlọ́run ẹni tí ó fì ìṣẹ́gun fún wá nípa Olúwa wá Jésù Kírísítì!

1 Kọ́ríńtì 15

1 Kọ́ríńtì 15:55-58