1 Kọ́ríńtì 15:55-58 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

55. “Ikú, oró rẹ dà?Ikú, iṣẹgun rẹ́ dà?”

56. Oró ikú ni ẹ̀ṣẹ̀; àti agbára ẹ̀ṣẹ̀ ni òfin

57. Ṣùgbọ́n ọpẹ́ ní fún Ọlọ́run ẹni tí ó fì ìṣẹ́gun fún wá nípa Olúwa wá Jésù Kírísítì!

58. Nítorí náà ẹ̀yín ará mi olùfẹ́ẹ̀ ẹ máa dúró ṣinṣin, láìyẹsẹ̀, kí ẹ máa pọ̀ si í ní iṣẹ́ Olúwa nígbà gbogbo, níwọn bí ẹyin ti mọ̀ pé iṣẹ́ yin kì í ṣe asán nínú Olúwa.

1 Kọ́ríńtì 15