1 Kíróníkà 7:36-40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

36. Àwọn ọmọ Ṣófáhì:Ṣúà, Háníférì, Ṣúálì, Bérì Ímírà.

37. Béṣérì Hódì, Ṣámà, Ṣílísà, Ítíránì àti Bérà.

38. Àwọn ọmọ Jétérì:Jéfúnè Písífà àti Árà.

39. Àwọn ọmọ Úlà:Árà Háníélì àti Résíà.

40. Gbogbo wọ̀nyí jẹ́ ìran ọmọ Áṣérì olórí ìdílé, àwọn okùnrin tí a yàn àwọn ògbóyà jagunjagun àti àwọn adarí tí ó dúró sinsin. Iye àwọn ọkùnrin tí ó setan fún ogun, gẹ́gẹ́ bí à ti se kọ ọ́ lẹ́sẹsẹ nínú ìtàn ìdílé wọn láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n.

1 Kíróníkà 7