1 Kíróníkà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ńjámínì jẹ́ bàbá Bélà àkọ́bí Rẹ̀,Áṣíbélì ọmọkùnrin ni ẹ̀ẹ̀kejì, Áhárá ẹ̀ẹ̀kẹ́ta,

1 Kíróníkà 8

1 Kíróníkà 8:1-3