1 Kíróníkà 6:27-31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

27. Élíábù ọmọ Rẹ̀,Jéríhámù ọmọ Rẹ̀, Élíkáná ọmọ Rẹ̀àti Ṣámúẹ́lì ọmọ Rẹ̀.

28. Àwọn ọmọ Ṣámúẹ́lì:Jóẹ́lì àkọ́bíàti Ábíjà ọmọẹlẹ́ẹ̀kejì.

29. Àwọn ìran ọmọ Mérárì:Máhílì, Líbínì ọmọ Rẹ̀.Ṣíméhì ọmọ Rẹ̀, Úṣáhì ọmọ Rẹ̀.

30. Ṣíméà, ọmọ Rẹ̀ Hágíáhì ọmọ Rẹ̀àti Ásáíáhì ọmọ Rẹ̀.

31. Èyí ní àwọn ọkùnrin Dáfídì tí a fi sí ìdí orin nínú ilé Olúwa lẹ́yìn tí àpótí ẹ̀rí ti wá láti sínmìn níbẹ̀.

1 Kíróníkà 6