1 Kíróníkà 6:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ní àwọn ọkùnrin Dáfídì tí a fi sí ìdí orin nínú ilé Olúwa lẹ́yìn tí àpótí ẹ̀rí ti wá láti sínmìn níbẹ̀.

1 Kíróníkà 6

1 Kíróníkà 6:25-33