1 Kíróníkà 29:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìn yìí, Ọlọ́run wa, àwa fi ọpẹ́ fún Ọ,a sì fi ìyìn fún orúkọ Rẹ̀ tí ó lógo.

1 Kíróníkà 29

1 Kíróníkà 29:8-18