1 Kíróníkà 29:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlá àti ọ̀wọ̀ wá láti ọ̀dọ̀ Rẹ;ìwọ ni alákòóso gbogbo nǹkan.Ní ọwọ́ rẹ ni ipá àti agbára wà láti gbéga àtiláti fi agbára fún ohun gbogbo.

1 Kíróníkà 29

1 Kíróníkà 29:2-16