1 Kíróníkà 27:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìkejìlá fún oṣù kejìlá jẹ́ Hélídáì ará Nétófátì láti ìdílé Ótíníélì. Ẹgbàá méjìlá ọkùnrin (24,000) ni ó wà ní ìpín tirẹ̀.

1 Kíróníkà 27

1 Kíróníkà 27:6-21