1 Kíróníkà 27:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìkọkànlá fún oṣù kọkànlá jẹ́ Bénáyà ará pírátónì ará Éfíráímù ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ni ó wà ní ìpín tirẹ̀.

1 Kíróníkà 27

1 Kíróníkà 27:12-19