1 Kíróníkà 26:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kèké fún ẹnu ọ̀nà ìhà gúṣù bọ́ sí ọ̀dọ̀ Obedì Édómù, kèké fún ilé ìṣúra sì bọ́ sí ọ̀dọ̀ ọmọ Rẹ̀.

1 Kíróníkà 26

1 Kíróníkà 26:13-18