1 Kíróníkà 26:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kèké fún ẹnu ọ̀nà ilà oòrùn bọ́ sí ọ̀dọ̀ Ṣélémíáyà, nígbà náà a dá kèké fún ọmọkùnrin rẹ̀ Ṣekaríáyà, ọlọ́gbọ́n onímọ̀ràn, kèké fún ẹnu ọ̀nà àríwá sì bọ́ sí ọ̀dọ̀ Rẹ̀.

1 Kíróníkà 26

1 Kíróníkà 26:12-23