1 Kíróníkà 18:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fi Gárísónì sí Édómù, gbogbo àwọn ará Édómù sì ń sìn ní abẹ́ Dáfídì. Olúwa fún Dáfídì ní ìṣẹ́gun ní gbogbo ibí tí ó bá lọ.

1 Kíróníkà 18

1 Kíróníkà 18:4-17