1 Kíróníkà 18:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábíṣáì ọmọ Ṣeruíà, lu méjìdínlógojì ẹgbẹ̀rin ará Édómù bolẹ̀ ní àfonífojì iyọ̀.

1 Kíróníkà 18

1 Kíróníkà 18:2-17