1 Kíróníkà 17:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò tí ì gbé nínú ilé láti ọjọ́ tí mo ti mú Isírẹ́lì jáde wá láti Éjíbítì títí di òní yìí. Èmi ń lọ láti àgọ́ dé àgọ́ àti láti ibùgbé dé ibùgbé.

1 Kíróníkà 17

1 Kíróníkà 17:1-11