1 Kíróníkà 17:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ sọ fún ìránṣẹ́ mi Dáfídì, ‘Èyí ni ohun tí Ọlọ́run wí: Ìwọ kò gbọdọ̀ kọ́ ilé fún mi láti máa gbé.

1 Kíróníkà 17

1 Kíróníkà 17:1-7