1 Kíróníkà 17:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nátanì dá Dáfídì lóhùn pé, Ohunkóhun tí o bá ní lọ́kàn, ṣe é nítorí tí Ọlọ́run wà pẹ̀lú rẹ.

1 Kíróníkà 17

1 Kíróníkà 17:1-5