1 Kíróníkà 16:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹ̀lú wọn ni Hémánì àti Jédútúnì àti ìyókù tí a mú àti yàn nípaṣẹ̀ orúkọ láti fi ọpẹ́ fún Olúwa Nítorí tí ìfẹ́ Rẹ̀ dúró títí láéláé

1 Kíróníkà 16

1 Kíróníkà 16:40-43