1 Kíróníkà 16:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti gbé pẹpẹ ọrẹ sísun déédé, àárọ̀ àti Ìrọ̀lẹ́ ní ìbámu pẹ̀lú gbogbo ohun tí a kọ sínú òfin Olúwa, tí ó ti fún Ísírẹ́lì.

1 Kíróníkà 16

1 Kíróníkà 16:30-43