1 Kíróníkà 15:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti Mátítíyà, Élíféléhù, Míkínéyà, Obedi-Édómù, Jélíélì àti Ásásíyà ni ó ní láti ta ohun èlò olóhùn goro, láti darí gẹ́gẹ́ bí Ṣémínítì.

1 Kíróníkà 15

1 Kíróníkà 15:17-26